ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 7:16-18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Jóṣúà wá dìde ní àárọ̀ kùtù ọjọ́ kejì, ó ní kí Ísírẹ́lì wá ní ẹ̀yà-ẹ̀yà, a sì mú ẹ̀yà Júdà. 17 Ó ní kí àwọn ìdílé Júdà wá, a sì mú ìdílé àwọn ọmọ Síírà,+ lẹ́yìn náà, ó ní kí àwọn ọkùnrin ní ìdílé àwọn ọmọ Síírà wá lọ́kọ̀ọ̀kan, a sì mú Sábídì. 18 Níkẹyìn, ó ní kí àwọn ọkùnrin ní agboolé Sábídí wá lọ́kọ̀ọ̀kan, a sì mú Ákánì ọmọ Kámì, ọmọ Sábídí, ọmọ Síírà látinú ẹ̀yà Júdà.+

  • Ìṣe 1:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Wọ́n wá gbàdúrà, wọ́n sì sọ pé: “Jèhófà,* ìwọ ẹni tó mọ ọkàn gbogbo èèyàn,+ fi ẹni tí o yàn lára àwọn ọkùnrin méjì yìí hàn,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́