Sáàmù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ṣe ni èmi yóò máa kọrin sí Jèhófà, nítorí ó ti san èrè fún mi lọ́pọ̀lọpọ̀.*+ Lúùkù 1:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Màríà wá sọ pé: “Ọkàn* mi gbé Jèhófà* ga,+