-
Léfítíkù 26:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Àmọ́, tí ẹ ò bá fetí sí mi, tí ẹ ò sì pa gbogbo àṣẹ yìí mọ́,+
-
-
Diutarónómì 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+
-
-
Jóṣúà 24:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Tí ẹ bá fi Jèhófà sílẹ̀, tí ẹ sì ń sin àwọn ọlọ́run àjèjì, òun náà máa kẹ̀yìn sí yín, ó sì máa pa yín run lẹ́yìn tó ti ṣe ohun rere fún yín.”+
-