ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 31:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Torí mo mọ̀ dáadáa pé tí mo bá ti kú, ó dájú pé ẹ máa ṣe ohun tó burú,+ ẹ sì máa yà kúrò lójú ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fún yín. Ó dájú pé àjálù máa dé bá yín+ nígbẹ̀yìn ọjọ́, torí ẹ máa ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, iṣẹ́ ọwọ́ yín sì máa múnú bí i.”

  • Jóṣúà 23:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Torí náà, ẹ jẹ́ onígboyà gidigidi kí ẹ lè máa pa gbogbo ohun tí a kọ sínú ìwé Òfin+ Mósè mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀ lé e, kí ẹ má ṣe yà kúrò nínú rẹ̀ sí ọ̀tún tàbí sí òsì,+

  • 1 Sámúẹ́lì 12:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àmọ́ tí ẹ kò bá ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, tí ẹ kò sì pa àṣẹ Jèhófà mọ́, ọwọ́ Jèhófà yóò le mọ́ ẹ̀yin àti àwọn bàbá yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́