1 Sámúẹ́lì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nígbà náà, Hánà dìde lẹ́yìn tí wọ́n ti parí jíjẹ àti mímu ní Ṣílò. Ní àkókò yẹn, àlùfáà Élì jókòó lórí ìjókòó tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ òpó ilẹ̀kùn tẹ́ńpìlì*+ Jèhófà.
9 Nígbà náà, Hánà dìde lẹ́yìn tí wọ́n ti parí jíjẹ àti mímu ní Ṣílò. Ní àkókò yẹn, àlùfáà Élì jókòó lórí ìjókòó tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ òpó ilẹ̀kùn tẹ́ńpìlì*+ Jèhófà.