1 Àwọn Ọba 1:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ni àlùfáà Sádókù bá mú ìwo òróró+ láti inú àgọ́,+ ó sì fòróró yan Sólómọ́nì,+ wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fun ìwo, gbogbo èèyàn náà sì ń kígbe pé: “Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!”
39 Ni àlùfáà Sádókù bá mú ìwo òróró+ láti inú àgọ́,+ ó sì fòróró yan Sólómọ́nì,+ wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í fun ìwo, gbogbo èèyàn náà sì ń kígbe pé: “Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!”