1 Kíróníkà 29:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu níwájú Jèhófà ní ọjọ́ yẹn tìdùnnútìdùnnú,+ wọ́n fi Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì jẹ ọba lẹ́ẹ̀kejì, wọ́n sì fòróró yàn án níwájú Jèhófà láti jẹ́ aṣáájú,+ bákan náà wọ́n yan Sádókù láti jẹ́ àlùfáà.+
22 Wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu níwájú Jèhófà ní ọjọ́ yẹn tìdùnnútìdùnnú,+ wọ́n fi Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì jẹ ọba lẹ́ẹ̀kejì, wọ́n sì fòróró yàn án níwájú Jèhófà láti jẹ́ aṣáájú,+ bákan náà wọ́n yan Sádókù láti jẹ́ àlùfáà.+