1 Sámúẹ́lì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ ní ti Sọ́ọ̀lù, ẹ̀mí Jèhófà ti kúrò lára rẹ̀,+ Jèhófà sì jẹ́ kí ẹ̀mí búburú máa dà á láàmú.+ 1 Sámúẹ́lì 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lọ́jọ́ kejì, Ọlọ́run jẹ́ kí ẹ̀mí búburú mú Sọ́ọ̀lù,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe wọ́nranwọ̀nran* nínú ilé, bí Dáfídì ṣe ń fi háàpù+ kọrin lọ́wọ́ bíi ti àtẹ̀yìnwá. Ọ̀kọ̀ kan wà lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù,+ 1 Sámúẹ́lì 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà jẹ́ kí ẹ̀mí búburú mú Sọ́ọ̀lù+ nígbà tó jókòó nínú ilé rẹ̀, tí ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì wà lọ́wọ́ rẹ̀, bí Dáfídì ṣe ń fi háàpù+ kọrin lọ́wọ́.
10 Lọ́jọ́ kejì, Ọlọ́run jẹ́ kí ẹ̀mí búburú mú Sọ́ọ̀lù,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe wọ́nranwọ̀nran* nínú ilé, bí Dáfídì ṣe ń fi háàpù+ kọrin lọ́wọ́ bíi ti àtẹ̀yìnwá. Ọ̀kọ̀ kan wà lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù,+
9 Jèhófà jẹ́ kí ẹ̀mí búburú mú Sọ́ọ̀lù+ nígbà tó jókòó nínú ilé rẹ̀, tí ọ̀kọ̀ rẹ̀ sì wà lọ́wọ́ rẹ̀, bí Dáfídì ṣe ń fi háàpù+ kọrin lọ́wọ́.