-
Jẹ́nẹ́sísì 35:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Lẹ́yìn náà, wọ́n ṣí kúrò ní Bẹ́tẹ́lì. Nígbà tí ọ̀nà wọn ṣì jìn díẹ̀ sí Éfúrátì, Réṣẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í rọbí, ó sì nira fún un gan-an.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 35:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Réṣẹ́lì wá kú, wọ́n sì sin ín ní ojú ọ̀nà Éfúrátì, ìyẹn Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.+
-