ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 15:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Kélẹ́bù sọ pé: “Ẹni tó bá pa Kiriati-séférì run, tó sì gbà á, màá fún un ní Ákúsà ọmọ mi pé kó fi ṣe aya.”

  • 1 Sámúẹ́lì 14:49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 Àwọn ọmọkùnrin Sọ́ọ̀lù ni Jónátánì, Íṣífì àti Maliki-ṣúà.+ Ó ní ọmọbìnrin méjì; èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Mérábù,+ àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Míkálì.+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Nígbà tó yá, Sọ́ọ̀lù sọ fún Dáfídì pé: “Wo Mérábù+ ọmọbìnrin mi àgbà. Màá fún ọ kí o fi ṣe aya.+ Síbẹ̀, jẹ́ kí n máa rí i pé o nígboyà, kí o sì máa ja àwọn ogun Jèhófà.”+ Torí Sọ́ọ̀lù sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: ‘Mi ò ní fi ọwọ́ ara mi pa á. Àwọn Filísínì ló máa pa á.’+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Torí náà, Sọ́ọ̀lù sọ pé: “Màá fi fún un kó lè di ìdẹkùn fún un, kí ọwọ́ àwọn Filísínì lè tẹ̀ ẹ́.”+ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún Dáfídì lẹ́ẹ̀kejì pé: “Wàá di àna* mi lónìí yìí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́