1 Sámúẹ́lì 17:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì ń sọ pé: “Ṣé ẹ rí ọkùnrin tó ń jáde bọ̀ yìí? Ńṣe ló wá pẹ̀gàn Ísírẹ́lì.*+ Ọrọ̀ tó pọ̀ ni ọba máa fún ọkùnrin tó bá mú un balẹ̀, á tún fún un ní ọmọbìnrin rẹ̀,+ ilé bàbá rẹ̀ kò sì ní san nǹkan kan mọ́ ní Ísírẹ́lì.”
25 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì ń sọ pé: “Ṣé ẹ rí ọkùnrin tó ń jáde bọ̀ yìí? Ńṣe ló wá pẹ̀gàn Ísírẹ́lì.*+ Ọrọ̀ tó pọ̀ ni ọba máa fún ọkùnrin tó bá mú un balẹ̀, á tún fún un ní ọmọbìnrin rẹ̀,+ ilé bàbá rẹ̀ kò sì ní san nǹkan kan mọ́ ní Ísírẹ́lì.”