1 Sámúẹ́lì 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọ̀kan lára àwọn ẹmẹ̀wà* sọ pé: “Wò ó! Mo ti rí bí ọ̀kan lára àwọn ọmọ Jésè ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ṣe ń ta háàpù dáadáa, onígboyà ni, jagunjagun tó lákíkanjú sì ni.+ Ó mọ̀rọ̀ọ́ sọ, ó rẹwà,+ Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀.”+
18 Ọ̀kan lára àwọn ẹmẹ̀wà* sọ pé: “Wò ó! Mo ti rí bí ọ̀kan lára àwọn ọmọ Jésè ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ṣe ń ta háàpù dáadáa, onígboyà ni, jagunjagun tó lákíkanjú sì ni.+ Ó mọ̀rọ̀ọ́ sọ, ó rẹwà,+ Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀.”+