Nọ́ńbà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+ Diutarónómì 33:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jẹ́ kí wọ́n fi àwọn ìdájọ́ rẹ kọ́ Jékọ́bù,+Kí wọ́n sì fi Òfin rẹ kọ́ Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ kí wọ́n sun tùràrí láti mú òórùn dídùn jáde sí ọ*+Àti odindi ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.+ Málákì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó yẹ kí ìmọ̀ máa wà ní ètè àlùfáà, ó sì yẹ kí àwọn èèyàn máa wá òfin* ní ẹnu rẹ̀,+ torí ìránṣẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni.
10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+
10 Jẹ́ kí wọ́n fi àwọn ìdájọ́ rẹ kọ́ Jékọ́bù,+Kí wọ́n sì fi Òfin rẹ kọ́ Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ kí wọ́n sun tùràrí láti mú òórùn dídùn jáde sí ọ*+Àti odindi ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.+
7 Ó yẹ kí ìmọ̀ máa wà ní ètè àlùfáà, ó sì yẹ kí àwọn èèyàn máa wá òfin* ní ẹnu rẹ̀,+ torí ìránṣẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni.