-
1 Sámúẹ́lì 16:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Sọ́ọ̀lù ránṣẹ́ sí Jésè pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí Dáfídì máa ṣe ìránṣẹ́ mi nìṣó, torí ó ti rí ojú rere mi.”
-
-
1 Sámúẹ́lì 17:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nígbà tí Dáfídì wà lọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù, ó máa ń lọ sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù láti lọ tọ́jú àwọn àgùntàn+ bàbá rẹ̀, á sì pa dà.
-