Jẹ́nẹ́sísì 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 àmọ́ kò ṣojúure sí Kéènì rárá, kò sì gba ọrẹ rẹ̀. Torí náà, Kéènì bínú gan-an, inú rẹ̀ ò sì dùn.* Òwe 14:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìbàlẹ̀ ọkàn ń mú kí ara lókun,*Àmọ́ owú dà bí àìsàn tó ń mú kí egungun jẹrà.+