Ẹ́kísódù 38:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. Léfítíkù 21:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí wọ́n jẹ́ mímọ́ sí Ọlọ́run wọn,+ kí wọ́n má sì sọ orúkọ Ọlọ́run wọn di aláìmọ́,+ torí àwọn ló ń mú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà wá, oúnjẹ* Ọlọ́run wọn, wọ́n gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́.+
8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.
6 Kí wọ́n jẹ́ mímọ́ sí Ọlọ́run wọn,+ kí wọ́n má sì sọ orúkọ Ọlọ́run wọn di aláìmọ́,+ torí àwọn ló ń mú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà wá, oúnjẹ* Ọlọ́run wọn, wọ́n gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́.+