-
1 Sámúẹ́lì 16:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Sámúẹ́lì ṣe ohun tí Jèhófà sọ. Nígbà tó dé Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ ẹ̀rù ń ba àwọn àgbààgbà ìlú nígbà tí wọ́n wá pàdé rẹ̀, wọ́n sọ pé: “Ṣé àlàáfíà lo bá wá?”
-