1 Sámúẹ́lì 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í jáde lọ, ó sì ń ṣàṣeyọrí*+ níbikíbi tí Sọ́ọ̀lù bá rán an. Torí náà, Sọ́ọ̀lù ní kó máa bójú tó àwọn jagunjagun,+ èyí sì dùn mọ́ gbogbo àwọn èèyàn náà nínú àti àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù pẹ̀lú. 1 Sámúẹ́lì 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, Sọ́ọ̀lù mú un kúrò níwájú rẹ̀, ó sì yàn án ṣe olórí ẹgbẹ̀rún, Dáfídì sì máa ń kó àwọn ọmọ ogun náà lọ sójú ogun.*+
5 Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í jáde lọ, ó sì ń ṣàṣeyọrí*+ níbikíbi tí Sọ́ọ̀lù bá rán an. Torí náà, Sọ́ọ̀lù ní kó máa bójú tó àwọn jagunjagun,+ èyí sì dùn mọ́ gbogbo àwọn èèyàn náà nínú àti àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù pẹ̀lú.
13 Torí náà, Sọ́ọ̀lù mú un kúrò níwájú rẹ̀, ó sì yàn án ṣe olórí ẹgbẹ̀rún, Dáfídì sì máa ń kó àwọn ọmọ ogun náà lọ sójú ogun.*+