2 Sámúẹ́lì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, nígbà tí Sọ́ọ̀lù jẹ́ ọba wa, ìwọ lò ń kó Ísírẹ́lì jáde ogun.*+ Jèhófà sì sọ fún ọ pé: ‘Ìwọ ni wàá máa bójú tó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì bí àgùntàn, wàá sì di aṣáájú Ísírẹ́lì.’”+
2 Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, nígbà tí Sọ́ọ̀lù jẹ́ ọba wa, ìwọ lò ń kó Ísírẹ́lì jáde ogun.*+ Jèhófà sì sọ fún ọ pé: ‘Ìwọ ni wàá máa bójú tó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì bí àgùntàn, wàá sì di aṣáájú Ísírẹ́lì.’”+