ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:14-16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 á sì tì í bọ inú agbada tàbí ìkòkò oníga méjì tàbí ìkòkò irin tàbí ìkòkò oníga kan. Ohunkóhun tí àmúga náà bá mú wá sókè ni àlùfáà yóò mú. Bí wọ́n ṣe ń ṣe nìyẹn ní Ṣílò sí gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń wá síbẹ̀. 15 Bákan náà, kí ọkùnrin tó ń rú ẹbọ tó mú ọ̀rá rú èéfín rárá,+ ìránṣẹ́ àlùfáà máa wá, á sì sọ fún un pé: “Fún àlùfáà ní ẹran tó máa yan. Kò ní gba ẹran bíbọ̀ lọ́wọ́ rẹ, àfi ẹran tútù.” 16 Nígbà tí ọkùnrin náà bá sọ fún un pé: “Jẹ́ kí wọ́n kọ́kọ́ mú ọ̀rá rú èéfín ná,+ lẹ́yìn ìyẹn, kí o mú ohun tí ọkàn rẹ bá fẹ́.”* Àmọ́ á sọ pé: “Rárá, fún mi báyìí-báyìí; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, màá mú un tipátipá!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́