Sáàmù 57:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Sí olùdarí; kí a yí i sí “Má Ṣe Pa Á Run.” Ti Dáfídì. Míkítámù.* Nígbà tó sá nítorí Sọ́ọ̀lù, tó sì lọ sínú ihò àpáta.+ Sáàmù 142:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tó wà nínú ihò àpáta.+ Àdúrà.
Sí olùdarí; kí a yí i sí “Má Ṣe Pa Á Run.” Ti Dáfídì. Míkítámù.* Nígbà tó sá nítorí Sọ́ọ̀lù, tó sì lọ sínú ihò àpáta.+