1 Sámúẹ́lì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀,+ ó sì sá lọ sí ihò Ádúlámù.+ Nígbà tí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀ gbọ́, wọ́n lọ bá a níbẹ̀. 1 Sámúẹ́lì 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Sọ́ọ̀lù dé ibi àwọn ọgbà àgùntàn tí wọ́n fi òkúta ṣe lójú ọ̀nà, níbi tí ihò kan wà, ó sì wọlé lọ láti tura,* àmọ́ Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ jókòó sí inú ihò náà ní apá ẹ̀yìn.+ Sáàmù 142:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tó wà nínú ihò àpáta.+ Àdúrà.
22 Nítorí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀,+ ó sì sá lọ sí ihò Ádúlámù.+ Nígbà tí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀ gbọ́, wọ́n lọ bá a níbẹ̀.
3 Sọ́ọ̀lù dé ibi àwọn ọgbà àgùntàn tí wọ́n fi òkúta ṣe lójú ọ̀nà, níbi tí ihò kan wà, ó sì wọlé lọ láti tura,* àmọ́ Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ jókòó sí inú ihò náà ní apá ẹ̀yìn.+