2 Sámúẹ́lì 24:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ ọkàn* Dáfídì dá a lẹ́bi+ lẹ́yìn tó ti ka iye àwọn èèyàn náà. Dáfídì wá sọ fún Jèhófà pé: “Mo ti dá ẹ̀ṣẹ̀+ ńlá nítorí ohun tí mo ṣe yìí. Ní báyìí, Jèhófà, jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ jì í,+ nítorí mo ti hùwà òmùgọ̀ gan-an.”+
10 Àmọ́ ọkàn* Dáfídì dá a lẹ́bi+ lẹ́yìn tó ti ka iye àwọn èèyàn náà. Dáfídì wá sọ fún Jèhófà pé: “Mo ti dá ẹ̀ṣẹ̀+ ńlá nítorí ohun tí mo ṣe yìí. Ní báyìí, Jèhófà, jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ jì í,+ nítorí mo ti hùwà òmùgọ̀ gan-an.”+