Léfítíkù 19:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi orúkọ mi búra èké,+ kí ẹ má bàa sọ orúkọ Ọlọ́run yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà. Diutarónómì 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o máa bẹ̀rù,+ òun ni kí o máa sìn,+ orúkọ rẹ̀ sì ni kí o máa fi búra.+