1 Sámúẹ́lì 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Dáfídì dúró sọ́dọ̀ Ákíṣì ní Gátì, òun àti àwọn ọkùnrin rẹ̀, kálukú pẹ̀lú agbo ilé rẹ̀. Àwọn ìyàwó Dáfídì méjèèjì sì wà pẹ̀lú rẹ̀, Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì àti Ábígẹ́lì,+ opó Nábálì, ará Kámẹ́lì.
3 Dáfídì dúró sọ́dọ̀ Ákíṣì ní Gátì, òun àti àwọn ọkùnrin rẹ̀, kálukú pẹ̀lú agbo ilé rẹ̀. Àwọn ìyàwó Dáfídì méjèèjì sì wà pẹ̀lú rẹ̀, Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì àti Ábígẹ́lì,+ opó Nábálì, ará Kámẹ́lì.