-
1 Sámúẹ́lì 15:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Sámúẹ́lì wá sọ fún un pé: “Jèhófà ti fa ìṣàkóso Ísírẹ́lì ya kúrò lọ́wọ́ rẹ lónìí, yóò sì fún ọmọnìkejì rẹ tó sàn jù ọ́ lọ.+
-
-
1 Àwọn Ọba 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 ìgbà náà ni màá fìdí ìtẹ́ ìjọba rẹ lórí Ísírẹ́lì múlẹ̀ títí láé, bí mo ti ṣèlérí fún Dáfídì bàbá rẹ pé, ‘Kò ní ṣàìsí ọkùnrin kan láti ìlà ìdílé rẹ tí yóò máa jókòó sórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì.’+
-