Léfítíkù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ohunkóhun tó bá ṣẹ́ kù lára ọrẹ ọkà náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́+ látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Nọ́ńbà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Kí gbogbo ọrẹ mímọ́ + tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá mú wá fún àlùfáà jẹ́ ti àlùfáà.+
3 Kí ohunkóhun tó bá ṣẹ́ kù lára ọrẹ ọkà náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́+ látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.