1 Sámúẹ́lì 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nábálì dá àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì lóhùn pé: “Ta ni Dáfídì, ta sì ni ọmọ Jésè? Lóde òní, ọ̀pọ̀ àwọn ìránṣẹ́ ló ń sá kúrò lọ́dọ̀ ọ̀gá wọn.+ 1 Sámúẹ́lì 25:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ní àkókò yìí, ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ Nábálì ròyìn fún Ábígẹ́lì, ìyàwó Nábálì pé: “Wò ó! Dáfídì rán àwọn òjíṣẹ́ láti aginjù kí wọ́n wá wo àlàáfíà ọ̀gá wa, àmọ́ ṣe ló fi ìbínú sọ̀rọ̀ burúkú sí wọn.+
10 Nábálì dá àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì lóhùn pé: “Ta ni Dáfídì, ta sì ni ọmọ Jésè? Lóde òní, ọ̀pọ̀ àwọn ìránṣẹ́ ló ń sá kúrò lọ́dọ̀ ọ̀gá wọn.+
14 Ní àkókò yìí, ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ Nábálì ròyìn fún Ábígẹ́lì, ìyàwó Nábálì pé: “Wò ó! Dáfídì rán àwọn òjíṣẹ́ láti aginjù kí wọ́n wá wo àlàáfíà ọ̀gá wa, àmọ́ ṣe ló fi ìbínú sọ̀rọ̀ burúkú sí wọn.+