-
Lúùkù 7:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Ó wá yíjú sí obìnrin náà, ó sì sọ fún Símónì pé: “Ṣé o rí obìnrin yìí? Mo wọ ilé rẹ; o ò fún mi ní omi láti fọ ẹsẹ̀ mi. Àmọ́ obìnrin yìí fi omijé rẹ̀ rin ẹsẹ̀ mi, ó sì fi irun rẹ̀ nù ún kúrò.
-