2 Sámúẹ́lì 3:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, Dáfídì rán àwọn òjíṣẹ́ sí Íṣí-bóṣétì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù, pé: “Fún mi ní Míkálì ìyàwó mi, ẹni tí mo fi ọgọ́rùn-ún (100) adọ̀dọ́ àwọn Filísínì+ fẹ́.” 15 Nítorí náà, Íṣí-bóṣétì ní kí wọ́n lọ mú un wá lọ́dọ̀ ọkọ rẹ̀, Pálítíélì+ ọmọ Láíṣì.
14 Lẹ́yìn náà, Dáfídì rán àwọn òjíṣẹ́ sí Íṣí-bóṣétì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù, pé: “Fún mi ní Míkálì ìyàwó mi, ẹni tí mo fi ọgọ́rùn-ún (100) adọ̀dọ́ àwọn Filísínì+ fẹ́.” 15 Nítorí náà, Íṣí-bóṣétì ní kí wọ́n lọ mú un wá lọ́dọ̀ ọkọ rẹ̀, Pálítíélì+ ọmọ Láíṣì.