ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 18:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Sọ́ọ̀lù wá sọ pé: “Ohun tí ẹ máa sọ fún Dáfídì nìyí, ‘Ọba ò fẹ́ nǹkan ìdána kankan,+ àfi ọgọ́rùn-ún (100) adọ̀dọ́+ àwọn Filísínì, kó lè gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀.’” Torí Sọ́ọ̀lù ń gbèrò pé kí Dáfídì ti ọwọ́ àwọn Filísínì ṣubú.

  • 1 Sámúẹ́lì 18:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ lọ, wọ́n sì pa igba (200) lára àwọn ọkùnrin Filísínì, Dáfídì kó gbogbo adọ̀dọ́ wọn wá fún ọba, kó lè bá ọba dána. Torí náà, Sọ́ọ̀lù fún un ní Míkálì ọmọ rẹ̀ láti fi ṣe aya.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́