7 Nígbà tí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì tó ń gbé ní agbègbè àfonífojì àti agbègbè ilẹ̀ Jọ́dánì rí i pé àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì ti sá lọ àti pé Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀ ti kú, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fi ìlú sílẹ̀, wọ́n sì sá lọ;+ lẹ́yìn náà, àwọn Filísínì wá, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀.