Léfítíkù 20:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ abẹ́mìílò tàbí woṣẹ́woṣẹ́.*+ Kí àwọn èèyàn sọ wọ́n lókùúta pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.’”
27 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ abẹ́mìílò tàbí woṣẹ́woṣẹ́.*+ Kí àwọn èèyàn sọ wọ́n lókùúta pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.’”