1 Sámúẹ́lì 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà yẹn, àwọn Filísínì kó àwọn ọmọ ogun wọn jọ láti bá Ísírẹ́lì jà.+ Nítorí náà, Ákíṣì sọ fún Dáfídì pé: “Ṣé o mọ̀ pé ìwọ àti àwọn ọkùnrin rẹ máa bá mi lọ jagun?”+
28 Nígbà yẹn, àwọn Filísínì kó àwọn ọmọ ogun wọn jọ láti bá Ísírẹ́lì jà.+ Nítorí náà, Ákíṣì sọ fún Dáfídì pé: “Ṣé o mọ̀ pé ìwọ àti àwọn ọkùnrin rẹ máa bá mi lọ jagun?”+