-
Jóṣúà 15:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ìlú tó wà ní ìkángun ẹ̀yà Júdà lápá ibi tí ààlà Édómù+ wà ní gúúsù nìyí: Kábúséélì, Édérì, Jágúrì,
-
-
Jóṣúà 15:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Síkílágì,+ Mádímánà, Sánsánà,
-
-
1 Sámúẹ́lì 27:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà náà, Dáfídì sọ fún Ákíṣì pé: “Tí mo bá rí ojú rere rẹ, jẹ́ kí wọ́n fún mi ní àyè nínú ọ̀kan lára àwọn ìlú tó wà ní ìgbèríko, kí n lè máa gbé ibẹ̀. Kí nìdí tí ìránṣẹ́ rẹ á fi máa bá ọ gbé nínú ìlú ọba?” 6 Torí náà, Ákíṣì fún un ní Síkílágì+ ní ọjọ́ yẹn. Ìdí nìyẹn tí Síkílágì fi jẹ́ ti àwọn ọba Júdà títí di òní yìí.
-