-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
Jóṣúà 15:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Ní agbègbè olókè, Ṣámírù, Játírì,+ Sókọ̀,
-
-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-