1 Sámúẹ́lì 14:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Ogun tó le ni àwọn Filísínì dojú kọ nígbà ayé Sọ́ọ̀lù.+ Tí Sọ́ọ̀lù bá sì rí ọkùnrin èyíkéyìí tó lágbára tàbí tó láyà, á gbà á síṣẹ́ ogun.+ 1 Sámúẹ́lì 29:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn Filísínì+ kó gbogbo ọmọ ogun wọn jọ sí Áfékì, nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ìsun tí ó wà ní Jésírẹ́lì.+
52 Ogun tó le ni àwọn Filísínì dojú kọ nígbà ayé Sọ́ọ̀lù.+ Tí Sọ́ọ̀lù bá sì rí ọkùnrin èyíkéyìí tó lágbára tàbí tó láyà, á gbà á síṣẹ́ ogun.+
29 Àwọn Filísínì+ kó gbogbo ọmọ ogun wọn jọ sí Áfékì, nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ìsun tí ó wà ní Jésírẹ́lì.+