2 Sámúẹ́lì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ má sọ ọ́ ní Gátì;+Ẹ má ṣe kéde rẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà Áṣíkẹ́lónì,Kí àwọn ọmọbìnrin Filísínì má bàa yọ̀,Kí àwọn ọmọbìnrin àwọn aláìdádọ̀dọ́* má bàa dunnú.
20 Ẹ má sọ ọ́ ní Gátì;+Ẹ má ṣe kéde rẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà Áṣíkẹ́lónì,Kí àwọn ọmọbìnrin Filísínì má bàa yọ̀,Kí àwọn ọmọbìnrin àwọn aláìdádọ̀dọ́* má bàa dunnú.