1 Sámúẹ́lì 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n gé orí rẹ̀ kúrò, wọ́n bọ́ ìhámọ́ra rẹ̀, wọ́n sì ránṣẹ́ sí gbogbo ilẹ̀ àwọn Filísínì pé kí wọ́n ròyìn rẹ̀ ní àwọn ilé*+ òrìṣà wọn+ àti láàárín àwọn èèyàn náà.
9 Wọ́n gé orí rẹ̀ kúrò, wọ́n bọ́ ìhámọ́ra rẹ̀, wọ́n sì ránṣẹ́ sí gbogbo ilẹ̀ àwọn Filísínì pé kí wọ́n ròyìn rẹ̀ ní àwọn ilé*+ òrìṣà wọn+ àti láàárín àwọn èèyàn náà.