ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ní gbogbo àkókò yìí, ọmọdékùnrin náà Sámúẹ́lì ń ṣe ìránṣẹ́+ fún Jèhófà níwájú Élì, àmọ́ ọ̀rọ̀ látọ̀dọ̀ Jèhófà ṣọ̀wọ́n lásìkò yẹn; ìran+ rírí kò sì wọ́pọ̀.

  • 1 Sámúẹ́lì 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jèhófà pe Sámúẹ́lì. Ó sì dáhùn pé: “Èmi nìyí.”

  • Sáàmù 99:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Mósè àti Áárónì wà lára àwọn àlùfáà rẹ̀,+

      Sámúẹ́lì sì wà lára àwọn tó ń ké pe orúkọ rẹ̀.+

      Wọ́n ń pe Jèhófà,

      Ó sì ń dá wọn lóhùn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́