1 Sámúẹ́lì 18:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Dáfídì ń ṣàṣeyọrí*+ nínú gbogbo ohun tó ń ṣe, Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀.+ 2 Sámúẹ́lì 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bí agbára Dáfídì ṣe ń pọ̀ sí i+ nìyẹn, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sì wà pẹ̀lú rẹ̀.+