-
Jẹ́nẹ́sísì 39:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àmọ́ Jèhófà wà pẹ̀lú Jósẹ́fù.+ Ìyẹn mú kó ṣàṣeyọrí, ọ̀gá rẹ̀ tó jẹ́ ará Íjíbítì sì fi ṣe alábòójútó ilé rẹ̀.
-
-
1 Sámúẹ́lì 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tí àmì wọ̀nyí bá ṣẹlẹ̀, ṣe gbogbo ohun tí o bá lè ṣe, torí pé Ọlọ́run tòótọ́ wà pẹ̀lú rẹ.
-