-
Nọ́ńbà 23:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Tó bá sọ ohun kan, ṣé kò ní ṣe é?
Tó bá sì sọ̀rọ̀, ǹjẹ́ kò ní mú un ṣẹ?+
-
-
Sáàmù 89:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Mo ti búra nínú ìjẹ́mímọ́ mi, lẹ́ẹ̀kan láìtún ṣe é mọ́;
Mi ò ní parọ́ fún Dáfídì.+
-
-
Sáàmù 132:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà ti búra fún Dáfídì,
Ó dájú pé kò ní ṣàìmú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ pé:
-