Sáàmù 89:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Mo ti rí Dáfídì ìránṣẹ́ mi;+Mo ti fi òróró mímọ́ mi yàn án.+ Sáàmù 89:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn ọmọ* rẹ̀ yóò wà títí láé;+Ìtẹ́ rẹ̀ yóò wà títí lọ bí oòrùn níwájú mi.+ Sáàmù 132:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+Àwọn ọmọ tiwọn náàYóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+
12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+Àwọn ọmọ tiwọn náàYóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+