2 Sámúẹ́lì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dáfídì fẹ́ àwọn wáhàrì*+ àti àwọn ìyàwó míì ní Jerúsálẹ́mù lẹ́yìn tí ó dé láti Hébúrónì, wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin púpọ̀ sí i fún Dáfídì.+ 2 Sámúẹ́lì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ló dé tí o kò fi ka ọ̀rọ̀ Jèhófà sí, tí o wá ṣe ohun tó burú lójú rẹ̀? O fi idà pa+ Ùráyà ọmọ Hétì! Lẹ́yìn náà, o sọ ìyàwó rẹ̀ di tìrẹ+ lẹ́yìn tí o ti mú kí idà àwọn ọmọ Ámónì pa á.+
13 Dáfídì fẹ́ àwọn wáhàrì*+ àti àwọn ìyàwó míì ní Jerúsálẹ́mù lẹ́yìn tí ó dé láti Hébúrónì, wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin púpọ̀ sí i fún Dáfídì.+
9 Kí ló dé tí o kò fi ka ọ̀rọ̀ Jèhófà sí, tí o wá ṣe ohun tó burú lójú rẹ̀? O fi idà pa+ Ùráyà ọmọ Hétì! Lẹ́yìn náà, o sọ ìyàwó rẹ̀ di tìrẹ+ lẹ́yìn tí o ti mú kí idà àwọn ọmọ Ámónì pa á.+