ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 11:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ó kọ ọ́ sínú lẹ́tà náà pé: “Ẹ fi Ùráyà síwájú níbi tí ogun ti le jù lọ. Lẹ́yìn náà kí ẹ pa dà lẹ́yìn rẹ̀, kí wọ́n lè mú un balẹ̀, kí ó sì kú.”+

  • 2 Sámúẹ́lì 11:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Gbàrà tí àkókò ọ̀fọ̀ náà parí, Dáfídì ránṣẹ́ sí i, ó mú un wá sí ilé rẹ̀, ó di ìyàwó rẹ̀,+ ó sì bí ọmọkùnrin kan fún un. Àmọ́ ohun tí Dáfídì ṣe yìí bí Jèhófà nínú* gan-an.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́