1 Kíróníkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn tí wọ́n bí fún un ní Jerúsálẹ́mù+ nìyí: Ṣíméà, Ṣóbábù, Nátánì+ àti Sólómọ́nì;+ ìyá àwọn mẹ́rin yìí ni Bátí-ṣébà+ ọmọbìnrin Ámíélì. 1 Kíróníkà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbogbo àwọn yìí ni ọmọ Dáfídì, yàtọ̀ sí àwọn ọmọ àwọn wáhàrì,* Támárì+ sì ni arábìnrin wọn. 1 Kíróníkà 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+ 1 Kíróníkà 28:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+ Mátíù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jésè bí Dáfídì+ ọba. Ìyàwó Ùráyà bí Sólómọ́nì+ fún Dáfídì;
5 Àwọn tí wọ́n bí fún un ní Jerúsálẹ́mù+ nìyí: Ṣíméà, Ṣóbábù, Nátánì+ àti Sólómọ́nì;+ ìyá àwọn mẹ́rin yìí ni Bátí-ṣébà+ ọmọbìnrin Ámíélì.
9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+
5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+