2 Sámúẹ́lì 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà náà, Dáfídì tu Bátí-ṣébà+ ìyàwó rẹ̀ nínú. Ó wọlé lọ bá a, ó sì bá a ní àṣepọ̀. Nígbà tó yá, ó bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sólómọ́nì.*+ Jèhófà sì nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+ 1 Kíróníkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn tí wọ́n bí fún un ní Jerúsálẹ́mù+ nìyí: Ṣíméà, Ṣóbábù, Nátánì+ àti Sólómọ́nì;+ ìyá àwọn mẹ́rin yìí ni Bátí-ṣébà+ ọmọbìnrin Ámíélì.
24 Nígbà náà, Dáfídì tu Bátí-ṣébà+ ìyàwó rẹ̀ nínú. Ó wọlé lọ bá a, ó sì bá a ní àṣepọ̀. Nígbà tó yá, ó bí ọmọkùnrin kan, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sólómọ́nì.*+ Jèhófà sì nífẹ̀ẹ́ rẹ̀,+
5 Àwọn tí wọ́n bí fún un ní Jerúsálẹ́mù+ nìyí: Ṣíméà, Ṣóbábù, Nátánì+ àti Sólómọ́nì;+ ìyá àwọn mẹ́rin yìí ni Bátí-ṣébà+ ọmọbìnrin Ámíélì.