ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 3:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Jáírì+ ọmọ Mánásè gba gbogbo agbègbè Ágóbù+ títí dé ààlà àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì,+ ó sì sọ àwọn abúlé Báṣánì yẹn ní orúkọ ara rẹ̀, ìyẹn Hafotu-jáírì*+ títí di òní olónìí.

  • Jóṣúà 12:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ó tún gba ilẹ̀ Ógù+ ọba Báṣánì tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Réfáímù+ tó kẹ́yìn, tó ń gbé ní Áṣítárótì àti Édíréì, 5 tó sì jọba ní Òkè Hámónì, ní Sálékà àti gbogbo Báṣánì,+ títí lọ dé ààlà àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì+ àti ìdajì Gílíádì, títí dé ilẹ̀ Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì.+

  • 2 Sámúẹ́lì 14:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ìgbà náà ni Jóábù gbéra, ó lọ sí Géṣúrì,+ ó sì mú Ábúsálómù wá sí Jerúsálẹ́mù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́