ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 17:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 ó ní: “Torí ó gbé ọwọ́ sókè sí ìtẹ́ Jáà,+ Jèhófà yóò máa gbógun ja Ámálékì láti ìran dé ìran.”+

  • Diutarónómì 25:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá ti mú kí o sinmi lọ́wọ́ gbogbo ọ̀tá rẹ tó yí ọ ká, ní ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ pé kí o jogún,+ kí o pa orúkọ Ámálékì rẹ́ kúrò lábẹ́ ọ̀run.+ O ò gbọ́dọ̀ gbàgbé.

  • 1 Sámúẹ́lì 15:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Ṣebí mo ti ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà! Mo lọ jíṣẹ́ tí Jèhófà rán mi, mo mú Ágágì ọba Ámálékì wá, mo sì pa àwọn ọmọ Ámálékì run pátápátá.+

  • 1 Sámúẹ́lì 30:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Nígbà tí Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ dé sí Síkílágì+ lọ́jọ́ kẹta, àwọn ọmọ Ámálékì+ ti wá kó ẹrù àwọn èèyàn ní gúúsù* àti ní Síkílágì, wọ́n ti gbéjà ko Síkílágì, wọ́n sì ti dáná sun ún.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́